ÌWÉ ÒWE 17:24

ÌWÉ ÒWE 17:24 YCE

Ẹni tí ó ní òye a máa tẹjúmọ́ ọgbọ́n, ṣugbọn ojú òmùgọ̀ kò gbé ibìkan, ó ń wo òpin ilẹ̀ ayé.