ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 7:22

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 7:22 YCE

Gbogbo ọgbọ́n àwọn ará Ijipti ni wọ́n fi kọ́ Mose. Ati ọ̀rọ̀ sísọ, ati iṣẹ́ ṣíṣe kò sí èyí tí kò mọ̀ ọ́n ṣe.