1
Gẹnẹsisi 7:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nígbà náà ni Ọlọ́run wí fún Noa pé, “Wọ inú ọkọ̀ lọ ìwọ àti gbogbo ìdílé rẹ, nítorí ìwọ nìkan ni mo rí bí olódodo nínú ìran yìí.
Paghambingin
I-explore Gẹnẹsisi 7:1
2
Gẹnẹsisi 7:24
Omi náà sì bo ilẹ̀ fún àádọ́jọ ọjọ́ (150).
I-explore Gẹnẹsisi 7:24
3
Gẹnẹsisi 7:11
Ní ọjọ́ kẹtà-dínlógún oṣù kejì, tí Noa pé ọmọ ẹgbẹ̀ta ọdún, ni gbogbo ìsun ibú ya, fèrèsé ìṣàn omi ọ̀run sì ṣí sílẹ̀.
I-explore Gẹnẹsisi 7:11
4
Gẹnẹsisi 7:23
Gbogbo ohun alààyè tí ó wà lórí ilẹ̀ ayé ni a parẹ́: ènìyàn àti ẹranko, àwọn ohun tí ń rìn nílẹ̀, àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run pátápátá ló ṣègbé. Noa àti àwọn tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ nínú ọkọ̀ ni ó ṣẹ́kù.
I-explore Gẹnẹsisi 7:23
5
Gẹnẹsisi 7:12
Òjò àrọ̀ìrọ̀dá sì rọ̀ fún ogójì ọ̀sán àti ogójì òru.
I-explore Gẹnẹsisi 7:12
Home
Biblia
Mga Gabay
Mga Palabas