1
JẸNẸSISI 2:24
Yoruba Bible
Ìdí nìyí tí ọkunrin yóo ṣe fi baba ati ìyá rẹ̀ sílẹ̀, tí yóo sì faramọ́ aya rẹ̀, àwọn mejeeji yóo sì di ara kan ṣoṣo.
Paghambingin
I-explore JẸNẸSISI 2:24
2
JẸNẸSISI 2:18
Lẹ́yìn náà OLUWA Ọlọrun sọ pé, “Kò dára kí ọkunrin náà nìkan dá wà, n óo ṣe olùrànlọ́wọ́ kan fún un, tí yóo dàbí rẹ̀.”
I-explore JẸNẸSISI 2:18
3
JẸNẸSISI 2:7
Nígbà náà ni OLUWA Ọlọrun bù ninu erùpẹ̀ ilẹ̀, ó fi mọ eniyan. Ó mí èémí ìyè sí ihò imú rẹ̀, eniyan sì di ẹ̀dá alààyè.
I-explore JẸNẸSISI 2:7
4
JẸNẸSISI 2:23
Ọkunrin náà bá wí pé, “Mo ṣẹ̀ṣẹ̀ rí ẹni tí ó dàbí mi, ẹni tí a mú jáde láti inú egungun ati ẹran ara mi; obinrin ni yóo máa jẹ́, nítorí pé láti ara ọkunrin ni a ti mú un jáde.”
I-explore JẸNẸSISI 2:23
5
JẸNẸSISI 2:3
Ó súre fún ọjọ́ keje yìí, ó sì yà á sí mímọ́, nítorí pé ọjọ́ náà ni ó sinmi ninu gbogbo iṣẹ́ ìṣẹ̀dá tí ó ti ń ṣe bọ̀.
I-explore JẸNẸSISI 2:3
6
JẸNẸSISI 2:25
Ọkunrin náà ati obinrin náà wà ní ìhòòhò, ojú kò sì tì wọ́n.
I-explore JẸNẸSISI 2:25
Home
Biblia
Mga Gabay
Mga Palabas