JẸNẸSISI 14:22-23

JẸNẸSISI 14:22-23 YCE

Ṣugbọn Abramu dá a lóhùn ó ní: “Mo ti búra fún OLUWA Ọlọrun Ọ̀gá Ògo, ẹni tí ó dá ọ̀run ati ayé, pé, abẹ́rẹ́ lásán, n kò ní fọwọ́ mi kàn ninu ohun tí ó jẹ́ tìrẹ, kí o má baà sọ pé ìwọ ni o sọ mí di ọlọ́rọ̀.

อ่าน JẸNẸSISI 14

วิดีโอสำหรับ JẸNẸSISI 14:22-23