1
JẸNẸSISI 40:8
Yoruba Bible
Wọ́n dá a lóhùn pé, “A lá àlá kan ni, a kò sì rí ẹni bá wa túmọ̀ rẹ̀.” Josẹfu dá wọn lóhùn, ó ní, “Ṣebí Ọlọrun ni ó ni ìtumọ̀ àlá? Ẹ rọ́ àlá náà fún mi.”
เปรียบเทียบ
สำรวจ JẸNẸSISI 40:8
2
JẸNẸSISI 40:23
Ṣugbọn olórí agbọ́tí kò ranti Josẹfu mọ, ó gbàgbé rẹ̀ patapata.
สำรวจ JẸNẸSISI 40:23
หน้าหลัก
พระคัมภีร์
แผนการอ่านต่างๆ
วิดีโอ