Gẹnẹsisi 24:12

Gẹnẹsisi 24:12 YCB

Ó sì gbàdúrà wí pé, “OLúWA, Ọlọ́run Abrahamu olúwa à mi; jẹ́ kí n ṣe àṣeyọrí lónìí, sì fi àánú hàn fún Abrahamu olúwa mi.