1
Gẹnẹsisi 29:20
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Jakọbu sì ṣiṣẹ́ sin Labani fún ọdún méje láti fẹ́ Rakeli. Àwọn ọdún wọ̀nyí sì dàbí ọjọ́ díẹ̀ lára rẹ̀, nítorí ó fẹ́ràn rẹ̀.
Bandingkan
Selidiki Gẹnẹsisi 29:20
2
Gẹnẹsisi 29:31
Nígbà tí Ọlọ́run sì ri pé, Jakọbu kò fẹ́ràn Lea, ó ṣí i ni inú ṣùgbọ́n Rakeli yàgàn.
Selidiki Gẹnẹsisi 29:31
Halaman Utama
Alkitab
Pelan
Video