1
Gẹn 7:1
Bibeli Mimọ
OLUWA si wi fun Noa pe, iwọ wá, ati gbogbo awọn ara ile rẹ sinu ọkọ̀, nitori iwọ ni mo ri li olododo niwaju mi ni iran yi.
Compare
Explore Gẹn 7:1
2
Gẹn 7:24
Omi si gbilẹ li aiye li ãdọjọ ọjọ́.
Explore Gẹn 7:24
3
Gẹn 7:11
Li ẹgbẹta ọdún ọjọ́ aiye Noa, li oṣù keji, ni ọjọ́ kẹtadinlogun oṣù, li ọjọ́ na ni gbogbo isun ibú nla ya, ati ferese iṣàn omi ọrun si ṣí silẹ.
Explore Gẹn 7:11
4
Gẹn 7:23
Ohun alãye gbogbo ti o wà lori ilẹ li a si parun, ati enia, ati ẹran-ọ̀sin, ati ohun ti nrakò, ati ẹiyẹ oju-ọrun, nwọn si run kuro lori ilẹ. Noa nikan li o kù, ati awọn ti o wà pẹlu rẹ̀ ninu ọkọ̀.
Explore Gẹn 7:23
5
Gẹn 7:12
Òjo na si wà lori ilẹ li ogoji ọsán on ogoji oru.
Explore Gẹn 7:12
Home
Bible
გეგმები
Videos