1
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:15
Yoruba Bible
Ìmọ̀ràn mi ni pé, kí eniyan máa gbádùn, nítorí kò sí ire kan tí ọmọ eniyan tún ń ṣe láyé ju pé kí ó jẹ, kí ó mu, kí ó sì gbádùn lọ; nítorí èyí ni yóo máa bá a lọ ní gbogbo ọjọ́ tí Ọlọrun fún un láyé.
Compare
Explore ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:15
2
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:12
Bí ẹlẹ́ṣẹ̀ tilẹ̀ ṣe ibi ní ọpọlọpọ ìgbà tí ọjọ́ rẹ̀ sì gùn, sibẹsibẹ mo mọ̀ pé yóo dára fún àwọn tí ó bẹ̀rù Ọlọrun.
Explore ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:12
3
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:6
Gbogbo nǹkan ló ní àkókò ati ìgbà tirẹ̀, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wahala wọ ẹ̀dá lọ́rùn.
Explore ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:6
4
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:8
Kò sí ẹni tí ó lágbára láti dá ẹ̀mí dúró, tabi láti yí ọjọ́ ikú pada, gbèsè ni ikú, kò sí ẹni tí kò ní san án; ìwà ibi àwọn tí ń ṣe ibi kò sì le gbà wọ́n sílẹ̀.
Explore ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:8
5
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:11
Nítorí pé wọn kì í tètè dá ẹjọ́ àwọn ẹni ibi, ni ọkàn ọmọ eniyan fi kún fún ìwà ibi.
Explore ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:11
6
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:14
Ohun asán kan tún wà tí ń ṣẹlẹ̀ nílé ayé yìí, a rí àwọn olódodo tí wọn ń jẹ ìyà àwọn eniyan burúkú, tí eniyan burúkú sì ń gba èrè olódodo, asán ni èyí pẹlu.
Explore ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:14
7
ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:7
Ẹnikẹ́ni kò mọ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn ọ̀la; ta ló lè sọ fún eniyan bí yóo ṣe ṣẹlẹ̀?
Explore ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 8:7
Home
Bible
Plans
Videos