1
TẸSALONIKA KEJI 3:3
Yoruba Bible
Ṣugbọn olódodo ni Oluwa, òun ni yóo fi ẹsẹ̀ yín múlẹ̀, tí yóo sì pa yín mọ́ kúrò ninu ibi gbogbo.
Compare
Explore TẸSALONIKA KEJI 3:3
2
TẸSALONIKA KEJI 3:5
Oluwa yóo tọ́ ọkàn yín láti mọ ìfẹ́ Ọlọrun ati ohun tí Kristi faradà nítorí yín.
Explore TẸSALONIKA KEJI 3:5
3
TẸSALONIKA KEJI 3:6
Ẹ̀yin ará, à ń pàṣẹ fun yín ní orúkọ Oluwa wa Jesu Kristi pé kí ẹ yẹra fún àwọn onigbagbọ tí wọn bá ń rìn ségesège, tí wọn kò tẹ̀lé ẹ̀kọ́ tí ẹ ti kọ́ lọ́dọ̀ wa.
Explore TẸSALONIKA KEJI 3:6
4
TẸSALONIKA KEJI 3:2
Kí ẹ tún máa gbadura pé kí Ọlọrun gbà wá lọ́wọ́ àwọn eniyan burúkú ati àwọn ìkà, nítorí kì í ṣe gbogbo eniyan ni ó gbàgbọ́.
Explore TẸSALONIKA KEJI 3:2
Home
Bible
Plans
Videos