1
Joh 1:12
Bibeli Mimọ
Ṣugbọn iye awọn ti o gbà a, awọn li o fi agbara fun lati di ọmọ Ọlọrun, ani awọn na ti o gbà orukọ rẹ̀ gbọ́
Cymharu
Archwiliwch Joh 1:12
2
Joh 1:1
LI àtetekọṣe li Ọ̀rọ wà, Ọ̀rọ si wà pẹlu Ọlọrun, Ọlọrun si li Ọ̀rọ na.
Archwiliwch Joh 1:1
3
Joh 1:5
Imọlẹ na si nmọlẹ ninu òkunkun; òkunkun na kò si bori rẹ̀.
Archwiliwch Joh 1:5
4
Joh 1:14
Ọ̀rọ na si di ara, on si mba wa gbé, (awa si nwò ogo rẹ̀, ogo bi ti ọmọ bíbi kanṣoṣo lati ọdọ Baba wá,) o kún fun ore-ọfẹ ati otitọ.
Archwiliwch Joh 1:14
5
Joh 1:3-4
Nipasẹ̀ rẹ̀ li a ti da ohun gbogbo; lẹhin rẹ̀ a ko si da ohun kan ninu ohun ti a da. Ninu rẹ̀ ni ìye wà; ìye na si ni imọlẹ̀ araiye.
Archwiliwch Joh 1:3-4
6
Joh 1:29
Ni ijọ keji Johanu ri Jesu mbọ̀ wá sọdọ rẹ̀; o wipe, Wò o, Ọdọ-agutan Ọlọrun, ẹniti o kó ẹ̀ṣẹ aiye lọ!
Archwiliwch Joh 1:29
7
Joh 1:10-11
On si wà li aiye, nipasẹ rẹ̀ li a si ti da aiye, aiye kò si mọ̀ ọ. O tọ̀ awọn tirẹ̀ wá, awọn ará tirẹ̀ kò si gbà a.
Archwiliwch Joh 1:10-11
8
Joh 1:9
Imọlẹ otitọ mbẹ ti ntàn mọlẹ fun olúkulùku enia ti o wá si aiye.
Archwiliwch Joh 1:9
9
Joh 1:17
Nitoripe nipasẹ Mose li a ti fi ofin funni, ṣugbọn ore-ọfẹ ati otitọ tipasẹ Jesu Kristi wá.
Archwiliwch Joh 1:17
Gartref
Beibl
Cynlluniau
Fideos