1
Gẹn 15:6
Bibeli Mimọ
O si gba OLUWA gbọ́; on si kà a si fun u li ododo.
Cymharu
Archwiliwch Gẹn 15:6
2
Gẹn 15:1
LẸHIN nkan wọnyi ọ̀rọ OLUWA tọ̀ Abramu wá li ojuran, wipe, Má bẹ̀ru, Abramu; Emi li asà rẹ, ère nla rẹ gidigidi.
Archwiliwch Gẹn 15:1
3
Gẹn 15:5
O si mu u jade wá si gbangba, o si wi pe, Gboju wò oke ọrun nisisiyi, ki o si kà irawọ bi iwọ ba le kà wọn: o si wi fun u pe, Bẹ̃ni irú-ọmọ rẹ yio ri.
Archwiliwch Gẹn 15:5
4
Gẹn 15:4
Si wo o, ọ̀rọ OLUWA tọ̀ ọ wá, wipe, Eleyi ki yio ṣe arole rẹ; bikoṣe ẹniti yio ti inu ara rẹ jade, on ni yio ṣe arole rẹ.
Archwiliwch Gẹn 15:4
5
Gẹn 15:13
On si wi fun Abramu pe, Mọ̀ nitõtọ pe irú-ọmọ rẹ yio ṣe alejo ni ilẹ ti ki iṣe ti wọn, nwọn o si sìn wọn, nwọn o si jẹ wọn ni íya ni irinwo ọdún
Archwiliwch Gẹn 15:13
6
Gẹn 15:2
Abramu si wipe, OLUWA Ọlọrun, kini iwọ o fi fun mi, emi sa nlọ li ailọmọ, Elieseri ti Damasku yi si ni ẹniti o ni ile mi?
Archwiliwch Gẹn 15:2
7
Gẹn 15:18
Li ọjọ́ na gan li OLUWA bá Abramu dá majẹmu pe, irú-ọmọ rẹ ni mo fi ilẹ yi fun, lati odò Egipti wá, titi o fi de odò nla nì, odò Euferate
Archwiliwch Gẹn 15:18
8
Gẹn 15:16
Ṣugbọn ni iran kẹrin, nwọn o si tun pada wá nihinyi: nitori ẹ̀ṣẹ awọn ara Amori kò ti ikún.
Archwiliwch Gẹn 15:16
Gartref
Beibl
Cynlluniau
Fideos