YouVersion Logo
Search Icon

Saamu 140:1-2

Saamu 140:1-2 YCB

OLúWA, gbà mi lọ́wọ́ ọkùnrin búburú u nì, yọ mí lọ́wọ́ ọkùnrin ìkà a nì; Ẹni tí ń ro ìwà búburú ní inú wọn; nígbà gbogbo ni wọ́n ń rú ìjà sókè sí mi.

Free Reading Plans and Devotionals related to Saamu 140:1-2