Esekiẹli 37:3
Esekiẹli 37:3 YCB
OLúWA sì bi mí léèrè, “Ọmọ ènìyàn, ǹjẹ́ àwọn egungun wọ̀nyí lè yípadà di àwọn ènìyàn bí?” Èmi sì wí pé, “Ìwọ OLúWA Olódùmarè, ìwọ nìkan ni o lè dáhùn sí ìbéèrè yìí.”