YouVersion Logo
Search Icon

Esekiẹli 12:28

Esekiẹli 12:28 YCB

“Nítorí náà sọ fún wọn, ‘Báyìí ni OLúWA Olódùmarè wí: Kò sí ọ̀kan nínú ọ̀rọ̀ mi tí yóò sún síwájú mọ́; ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ tí mo bá sọ yóò ṣẹ.’ ”