YouVersion Logo
Search Icon

Esekiẹli 11:17

Esekiẹli 11:17 YCB

“Nítorí náà, wí pé: ‘Báyìí ni OLúWA Olódùmarè wí: Èmi yóò kó wọn jọ kúrò láàrín àwọn orílẹ̀-èdè tí mo fọ́n wọn ká sí, Èmi yóò sì fún wọn ní ilẹ̀ Israẹli padà.’