YouVersion Logo
Search Icon

Eksodu 36:1

Eksodu 36:1 YCB

Besaleli, Oholiabu àti olúkúlùkù ọlọ́gbọ́n ẹni tí OLúWA tí fún ní ọgbọ́n àti òye láti mọ bí a ti í ṣe gbogbo iṣẹ́ ibi mímọ́ ni kí wọn ṣe iṣẹ́ náà gẹ́gẹ́ bí OLúWA ti pa á láṣẹ.”