YouVersion Logo
Search Icon

Amosi 1:1-2

Amosi 1:1-2 YCB

Àwọn ọ̀rọ̀ Amosi, ọ̀kan lára àwọn olùṣọ́-àgùntàn Tekoa; ohun tí o rí nípa Israẹli ní ọdún méjì ṣáájú ilẹ̀-rírì, nígbà tí Ussiah ọba Juda àti Jeroboamu ọmọ Jehoaṣi jẹ́ ọba ní ilẹ̀ Israẹli. Ó wí pé: “OLúWA yóò bú jáde láti Sioni ohùn rẹ̀ yóò sì sán bí àrá láti Jerusalẹmu wá; Ibùgbé àwọn olùṣọ́-àgùntàn yóò sì ṣọ̀fọ̀, orí òkè Karmeli yóò sì rọ.”