YouVersion Logo
Search Icon

2 Kronika 33:12-13

2 Kronika 33:12-13 YCB

Nínú ìpọ́njú rẹ̀, ó wá ojúrere OLúWA Ọlọ́run rẹ̀. Ó sì rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ gidigidi níwájú Ọlọ́run àwọn baba rẹ̀. Nígbà tí ó sì gbàdúrà sí i, inú OLúWA dùn sí àdúrà rẹ̀, ó sì tẹ́tí sí ẹ̀bẹ̀ rẹ̀; bẹ́ẹ̀ ni ó mú un padà wá sí Jerusalẹmu àti sí ìjọba rẹ̀. Nígbà náà Manase mọ̀ wí pé OLúWA ni Ọlọ́run.