YouVersion Logo
Search Icon

ÌFIHÀN 7:9

ÌFIHÀN 7:9 YCE

Lẹ́yìn náà, mo rí ọ̀pọ̀ eniyan tí ẹnikẹ́ni kò lè kà láti gbogbo orílẹ̀-èdè ati ẹ̀yà, ati oríṣìíríṣìí èdè, wọ́n dúró níwájú ìtẹ́ náà ati níwájú Ọ̀dọ́ Aguntan. Wọ́n wọ aṣọ funfun. Wọ́n mú imọ̀ ọ̀pẹ lọ́wọ́.

Video for ÌFIHÀN 7:9

Free Reading Plans and Devotionals related to ÌFIHÀN 7:9