YouVersion Logo
Search Icon

ORIN DAFIDI 137:3-4

ORIN DAFIDI 137:3-4 YCE

nítorí pé níbẹ̀ ni àwọn tí ó kó wa ní ìgbèkùn ti ní kí á kọrin fún àwọn. Àwọn tí ó ń pọ́n wa lójú sọ pé kí á dá àwọn lárayá, wọ́n ní, “Ẹ kọ orin Sioni kan fún wa.” Báwo ni a óo ṣe kọ orin OLUWA ní ilẹ̀ àjèjì?