ORIN DAFIDI 10:17-18
ORIN DAFIDI 10:17-18 YCE
OLUWA, o óo gbọ́ igbe àwọn tí a nilára; o óo mú wọn lọ́kàn le, o óo sì dẹ etí sílẹ̀ sí igbe wọn kí o lè ṣe ẹ̀tọ́ fún àwọn aláìníbaba ati àwọn ẹni tí à ń pọ́n lójú, kí ọmọ eniyan, erùpẹ̀ lásánlàsàn, má lè dẹ́rù bani mọ́.