YouVersion Logo
Search Icon

ẸKÚN JEREMAYA 2:19

ẸKÚN JEREMAYA 2:19 YCE

Ẹ dìde, ẹ kígbe lálẹ́, ní àkókò tí àwọn aṣọ́de ń bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́! Ẹ tú ẹ̀dùn ọkàn yín jáde bí omi níwájú OLUWA! Ẹ gbé ọwọ́ ẹ̀bẹ̀ sókè sí i, nítorí ẹ̀mí àwọn ọmọ yín tí ebi ń pa kú lọ ní gbogbo ìkóríta.

Video for ẸKÚN JEREMAYA 2:19

Free Reading Plans and Devotionals related to ẸKÚN JEREMAYA 2:19