ÀWỌN ỌBA KEJI 22:20
ÀWỌN ỌBA KEJI 22:20 YCE
Nítorí náà, n kò ní fi ìyà jẹ Jerusalẹmu nígbà tí ó wà láàyè, n óo jẹ́ kí ó kú ní alaafia.” ’ ” Àwọn ọkunrin náà sì lọ jíṣẹ́ fún Josaya ọba.