1
Saamu 9:10
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Àwọn tí ó mọ orúkọ rẹ yóò gbẹ́kẹ̀lé ọ, nítorí, OLúWA, kò kọ àwọn tó ń wá a sílẹ̀.
Compare
Explore Saamu 9:10
2
Saamu 9:1
Èmi ó yìn ọ́, OLúWA, pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi; Èmi ó sọ ti ìyanu rẹ gbogbo.
Explore Saamu 9:1
3
Saamu 9:9
OLúWA ni ààbò fún àwọn tí a ni lára, ibi ìsádi ní àkókò ìpọ́njú.
Explore Saamu 9:9
4
Saamu 9:2
Inú mi yóò dùn, èmi yóò sì yọ̀ nínú rẹ; Èmi ó kọrin ìyìn sí orúkọ rẹ, Ìwọ Ọ̀gá-Ògo jùlọ.
Explore Saamu 9:2
5
Saamu 9:8
Òun yóò sì ṣe ìdájọ́ ayé ní òdodo; yóò ṣe àkóso ènìyàn pẹ̀lú òdodo.
Explore Saamu 9:8
Home
Bible
Plans
Videos