1
Saamu 64:10
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Jẹ́ kí olódodo kí ó yọ̀ nínú OLúWA yóò sì rí ààbò nínú rẹ̀. Gbogbo ẹni ìdúró ṣinṣin ní ọkàn yóò máa yìn ín.
Compare
Explore Saamu 64:10
2
Saamu 64:1
Gbóhùn mi, Ọlọ́run, bí mo ti ń sọ àròyé mi pa ọkàn mi mọ́ kúrò lọ́wọ́ ẹ̀rù àwọn ọ̀tá.
Explore Saamu 64:1
Home
Bible
Plans
Videos