1
Saamu 6:9
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
OLúWA ti gbọ́ ẹkún mi fún àánú; OLúWA ti gba àdúrà mi.
Compare
Explore Saamu 6:9
2
Saamu 6:2
Ṣàánú fún mi, OLúWA, nítorí èmi ń kú lọ; OLúWA, wò mí sán, nítorí egungun mi wà nínú ìnira.
Explore Saamu 6:2
3
Saamu 6:8
Kúrò lọ́dọ̀ mi, gbogbo ẹ̀yin tí ń ṣe iṣẹ́ ibi, nítorí OLúWA ti gbọ́ igbe mi.
Explore Saamu 6:8
4
Saamu 6:4
Yípadà, OLúWA, kí o sì gbà mí; gbà mí là nípa ìfẹ́ rẹ tí kì í ṣákì í.
Explore Saamu 6:4
Home
Bible
Plans
Videos