1
Saamu 30:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí pé ìbínú rẹ̀ wà fún ìgbà díẹ̀, ojúrere rẹ̀ wà títí ayérayé; Ẹkún lè pẹ́ títí di alẹ́, Ṣùgbọ́n ayọ̀ yóò wá ní òwúrọ̀.
Compare
Explore Saamu 30:5
2
Saamu 30:11-12
Ìwọ ti yí ìkáàánú mi di ijó fún mi; ìwọ sì ti bọ́ aṣọ ọ̀fọ̀ mi, o sì fi aṣọ ayọ̀ wọ̀ mí, nítorí ìdí èyí ni kí ọkàn mi máa yìn ọ́, kí o má sì ṣe dákẹ́. Ìwọ OLúWA Ọlọ́run mi, èmi yóò máa fi ọpẹ́ fún ọ títí láé.
Explore Saamu 30:11-12
3
Saamu 30:2
OLúWA Ọlọ́run mi, èmi ké pè ọ́, fún ìrànlọ́wọ́ ìwọ sì ti wò mí sàn.
Explore Saamu 30:2
4
Saamu 30:4
Kọ orin ìyìn sí OLúWA, ẹ̀yin olódodo; kí ẹ sì fi ọpẹ́ fún orúkọ rẹ̀ mímọ́.
Explore Saamu 30:4
5
Saamu 30:1
Èmi yóò kókìkí i rẹ, OLúWA, nítorí ìwọ ni ó gbé mi lékè tí ìwọ kò sì jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mi kí ó yọ̀ mí.
Explore Saamu 30:1
Home
Bible
Plans
Videos