1
Saamu 122:6-8
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Gbàdúrà fún àlàáfíà Jerusalẹmu; àwọn tí ó fẹ́ ọ yóò ṣe rere. Kí àlàáfíà kí ó wà nínú odi rẹ̀, àti ìre nínú ààfin rẹ̀. Nítorí àwọn ọkùnrin àti àwọn ẹgbẹ́ mi èmi yóò wí nísinsin yìí pé, kí àlàáfíà kí ó wà nínú rẹ̀
Compare
Explore Saamu 122:6-8
Home
Bible
Plans
Videos