1
Saamu 118:24
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èyí ni ọjọ́ tí OLúWA dá: ẹ jẹ́ kí ayọ̀ kí inú wa sì máa dùn nínú rẹ̀.
Compare
Explore Saamu 118:24
2
Saamu 118:6
OLúWA ń bẹ fún èmi; èmi kì yóò bẹ̀rù. Kí ni ènìyàn lè ṣe sí mi?
Explore Saamu 118:6
3
Saamu 118:8
Ó dára láti máa gbẹ́kẹ̀lé OLúWA ju àti gbẹ́kẹ̀lé ènìyàn lọ.
Explore Saamu 118:8
4
Saamu 118:5
Nínú ìrora mi, mo sọkún sí OLúWA, ó sì dá mi lóhùn nípa pé ó tú mi sílẹ̀.
Explore Saamu 118:5
5
Saamu 118:29
Ẹ fi ọpẹ́ fún OLúWA, nítorí tí ó ṣeun; nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé.
Explore Saamu 118:29
6
Saamu 118:1
Ẹ fi ọpẹ́ fún OLúWA, nítorí tí ó dára; àánú rẹ̀ dúró láéláé.
Explore Saamu 118:1
7
Saamu 118:14
OLúWA ni agbára àti orin mi; ó sì di ìgbàlà mi.
Explore Saamu 118:14
8
Saamu 118:9
Ó dára láti máa gbẹ́kẹ̀lé OLúWA ju à ti gbẹ́kẹ̀lé àwọn ọmọ-aládé lọ.
Explore Saamu 118:9
9
Saamu 118:22
Òkúta tí àwọn ọ̀mọ̀lé kọ̀sílẹ̀, ni ó di pàtàkì igun ilé
Explore Saamu 118:22
Home
Bible
Plans
Videos