1
Òwe 5:21
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí ọ̀nà ènìyàn kò fi ara sin rárá fún OLúWA Ó sì ń gbé gbogbo ọ̀nà rẹ̀ yẹ̀ wò
Compare
Explore Òwe 5:21
2
Òwe 5:15
Mu omi láti inú kànga tìrẹ Omi tí ń sàn láti inú kànga rẹ.
Explore Òwe 5:15
3
Òwe 5:22
Ìwà búburú ènìyàn búburú ni yóò mú kó bọ́ sínú okùn; okùn ẹ̀ṣẹ̀ ara rẹ̀ yóò sì dìímú.
Explore Òwe 5:22
4
Òwe 5:3-4
Nítorí ètè àwọn àjèjì obìnrin a máa sun bi oyin, ọ̀rọ̀ rẹ̀ sì kúnná ju òróró lọ. Ṣùgbọ́n ní ìgbẹ̀yìn gbẹ́yín, ó korò ju òróǹró lọ, ó mú bí idà olójú méjì.
Explore Òwe 5:3-4
Home
Bible
Plans
Videos