1
Òwe 31:30
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ojú dáradára a máa tan ni, ẹwà sì jẹ́ asán nítorí obìnrin tí ó bẹ̀rù OLúWA yẹ kí ó gba oríyìn
Compare
Explore Òwe 31:30
2
Òwe 31:25-26
Agbára àti ọlá ni ó wò ọ́ láṣọ ó le fi ọjọ́ iwájú rẹ́rìn-ín. A sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ọgbọ́n ìkọ́ni òtítọ́ sì ń bẹ létè e rẹ̀
Explore Òwe 31:25-26
3
Òwe 31:20
O la ọwọ́ rẹ̀ sí àwọn tálákà ó sì na ọwọ́ rẹ̀ sí àwọn aláìní.
Explore Òwe 31:20
4
Òwe 31:10
Ta ni ó le rí aya oníwà rere? Ó níye lórí ju iyùn lọ
Explore Òwe 31:10
5
Òwe 31:31
Sì fún un ní èrè tí ó tọ́ sí i kí o sì jẹ́ kí iṣẹ́ rẹ̀ fún un ní ìyìn ní ẹnu ibodè ìlú.
Explore Òwe 31:31
6
Òwe 31:28
Àwọn ọmọ rẹ̀ dìde wọ́n sì pè é ní alábùkún ọkọ rẹ̀ pẹ̀lú ń gbóríyìn fún un
Explore Òwe 31:28
Home
Bible
Plans
Videos