1
Jona 2:2
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ó sì wí pé: “Nínú ìpọ́njú mi ni mo kígbe sí OLúWA, òun sì gbọ́ ohùn mi. Mo kígbe láti inú ipò òkú, mo pè fún ìrànwọ́, ìwọ sì gbọ́ ohùn mi.
Compare
Explore Jona 2:2
2
Jona 2:7
“Nígbà tí ó rẹ ọkàn mi nínú mi, èmi rántí rẹ, OLúWA, àdúrà mi sì wá sí ọ̀dọ̀ rẹ, nínú tẹmpili mímọ́ rẹ.
Explore Jona 2:7
Home
Bible
Plans
Videos