1
Jobu 9:10
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ẹni tí ń ṣe ohun tí ó tóbi jù àwárí lọ, àní ohun ìyanu láìní iye.
Compare
Explore Jobu 9:10
2
Jobu 9:4
Ọlọ́gbọ́n nínú àwọn alágbára ní ipa ní Òun; ta ni ó ṣe agídí sí i tí ó sì gbé fún rí?
Explore Jobu 9:4
Home
Bible
Plans
Videos