1
Jeremiah 37:17
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nígbà náà ni ọba Sedekiah ránṣẹ́ sí i, tí ó sì pàṣẹ pé kí wọ́n mú wá sí ààfin níbi tí ó ti bi í ní ìkọ̀kọ̀ pé, “Ǹjẹ́ ọ̀rọ̀ kan wà láti ọ̀dọ̀ OLúWA?” “Bẹ́ẹ̀ ni,” Jeremiah fèsì pé, “wọn ó fi ọ́ lé ọwọ́ ọba Babeli.”
Compare
Explore Jeremiah 37:17
2
Jeremiah 37:15
Nítorí náà ni àwọn ìjòyè ṣe bínú sí Jeremiah, wọ́n jẹ ẹ́ ní yà, wọ́n tún fi sí túbú nílé Jonatani akọ̀wé nítorí wọ́n ti fi èyí ṣe ilé túbú.
Explore Jeremiah 37:15
3
Jeremiah 37:2
Ṣùgbọ́n àti òun àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ àti àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà kò fetísí ọ̀rọ̀ OLúWA tí ó sọ nípa wòlíì Jeremiah.
Explore Jeremiah 37:2
4
Jeremiah 37:9
“Èyí ni ohun tí Ọlọ́run wí: Ẹ má ṣe tan ara yín jẹ ní èrò wí pé, ‘Àwọn ará Babeli yóò fi wá sílẹ̀ pẹ̀lú ìdánilójú;’ wọn kò ní ṣe bẹ́ẹ̀.
Explore Jeremiah 37:9
Home
Bible
Plans
Videos