1
Onidajọ 14:6
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ẹ̀mí OLúWA sì bà lé e pẹ̀lú agbára tó bẹ́ẹ̀ tí ó fi fa kìnnìún náà ya pẹ̀lú ọwọ́ rẹ̀ lásán bí ẹní ya ọmọ ewúrẹ́, ṣùgbọ́n òun kò sọ ohun tí ó ṣe fún baba tàbí ìyá rẹ̀.
Compare
Explore Onidajọ 14:6
Home
Bible
Plans
Videos