1
Hosea 10:12
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ẹ gbin òdòdó fún ara yín, kí ẹ sì ká èso ìfẹ́ àìlópin, Ẹ tu ilẹ̀ yín tí a kò ro, nítorí pé ó ti tó àsìkò láti wá OLúWA, títí tí yóò fi dé, tí yóò sì rọ òjò òdodo lé yín lórí.
Compare
Explore Hosea 10:12
2
Hosea 10:13
Ṣùgbọ́n ẹ tí gbin búburú ẹ si ka ibi, Ẹ ti jẹ èso èké nítorí ẹ tí gbẹ́kẹ̀lé agbára yín àti àwọn ọ̀pọ̀ jagunjagun yín
Explore Hosea 10:13
Home
Bible
Plans
Videos