1
Esekiẹli 39:29
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èmi kì yóò sì fi ojú mi pamọ́ kúrò lọ́dọ̀ wọn mọ nítorí èmi yóò tú èémí mi jáde sí ilé Israẹli, ní OLúWA Olódùmarè wí.”
Compare
Explore Esekiẹli 39:29
2
Esekiẹli 39:28
Nígbà náà, wọn yóò mọ̀ pé èmi ni OLúWA Ọlọ́run wọn nítorí bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé mo rán wọn lọ sí ìgbèkùn láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, èmi yóò kó wọn jọ sí orí ilẹ̀ wọn, láìfi nǹkan kan sẹ́yìn.
Explore Esekiẹli 39:28
3
Esekiẹli 39:25
“Nítorí náà èyí ni ohun tí OLúWA Olódùmarè wí: Èmi yóò mú Jakọbu padà kúrò ní oko ẹrú, èmi yóò ní ìyọ́nú si gbogbo ènìyàn Israẹli, èmi yóò sì ní ìtara fún orúkọ mímọ́ mi.
Explore Esekiẹli 39:25
Home
Bible
Plans
Videos