1
Eksodu 14:14
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
OLúWA yóò jà fún un yín; kí ẹ̀yin kí ó sá à mu sùúrù.”
Compare
Explore Eksodu 14:14
2
Eksodu 14:13
Nígbà náà ni Mose sọ fún àwọn ènìyàn náà pé, “Ẹ má bẹ̀rù, ẹ dúró ṣinṣin kí ẹ sì rí ìdáǹdè tí OLúWA yóò fi fún un yín lónìí; Àwọn ará Ejibiti ti ẹ̀yin rí lónìí ni ẹ kò ni tún padà rí wọn mọ́.
Explore Eksodu 14:13
3
Eksodu 14:16
Ṣùgbọ́n, gbé ọ̀pá rẹ̀ sókè, kí o sì na ọwọ́ rẹ sí orí omi Òkun, kí ó lè pín ní yà kí àwọn ọmọ Israẹli lè la Òkun kọjá ni orí ìyàngbẹ ilẹ̀.
Explore Eksodu 14:16
4
Eksodu 14:31
Nígbà ti àwọn ọmọ Israẹli rí iṣẹ́ ìyanu ńlá ti OLúWA ṣe fún wọn lára àwọn ará Ejibiti, àwọn ènìyàn bẹ̀rù OLúWA, wọ́n sì gba OLúWA àti Mose ìránṣẹ́ rẹ gbọ́.
Explore Eksodu 14:31
Home
Bible
Plans
Videos