1
Deuteronomi 2:7
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
OLúWA Ọlọ́run yín ti bùkún un yín nínú gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ yín. Ó ti mójútó ìrìnàjò yín nínú aginjù ńlá yìí. OLúWA Ọlọ́run yín wà pẹ̀lú u yín ní ogójì ọdún wọ̀nyí, dé bi pé ẹ̀yin kò ṣaláìní ohunkóhun.
Compare
Explore Deuteronomi 2:7
Home
Bible
Plans
Videos