1
Deuteronomi 16:17
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Kí olúkúlùkù ó mú ọrẹ wá bí agbára rẹ̀ ti tó, gẹ́gẹ́ bí ìbùkún OLúWA Ọlọ́run rẹ tí ó fi fún un ọ̀.
Compare
Explore Deuteronomi 16:17
2
Deuteronomi 16:19
Ìwọ kò gbọdọ̀ yí ìdájọ́ po, ìwọ kò gbọdọ̀ ṣe ojúsàájú ènìyàn. Ìwọ kò gbọdọ̀ gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ nítorí pé àbẹ̀tẹ́lẹ̀ ń fọ́ ojú ọlọ́gbọ́n, ó sì ń ba ọ̀rọ̀ olódodo jẹ́.
Explore Deuteronomi 16:19
3
Deuteronomi 16:16
Ní ẹ̀ẹ̀mẹ́ta lọ́dún ni kí gbogbo àwọn ọkùnrin rẹ kí ó farahàn níwájú OLúWA Ọlọ́run rẹ̀, ní ibi tí yóò yàn. Níbi àjọ àkàrà àìwú, níbi àjọ ọ̀sẹ̀, àti àjọ àgọ́ ìpàdé. Ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ wá sí iwájú OLúWA ní ọwọ́ òfo.
Explore Deuteronomi 16:16
4
Deuteronomi 16:20
Ẹ tẹ̀lé ìdájọ́ òtítọ́ àní ìdájọ́ òtítọ́ nìkan, kí ẹ bá à lè gbé kí ẹ sì gba ilẹ̀ tí OLúWA Ọlọ́run yín ń fún un yín.
Explore Deuteronomi 16:20
Home
Bible
Plans
Videos