1
Deuteronomi 14:22
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ẹ rí i dájú pé ẹ̀ ń fi ìdákan nínú mẹ́wàá nínú ìre oko yín lọ́dọọdún pamọ́ sí apá kan
Compare
Explore Deuteronomi 14:22
2
Deuteronomi 14:23
Ẹ jẹ ìdámẹ́wàá oúnjẹ yín, wáìnì tuntun, òróró, àti àkọ́bí àwọn màlúù yín àti ewúrẹ́ ẹ yín, níwájú OLúWA Ọlọ́run yín, ní ibi tí yóò yàn bí ibùgbé orúkọ rẹ̀. Kí ẹ lè kọ́ bí a ṣé ń bu ọlá fún OLúWA Ọlọ́run yín nígbà gbogbo.
Explore Deuteronomi 14:23
Home
Bible
Plans
Videos