1
2 Samuẹli 3:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ogun náà sì pẹ́ títí láàrín ìdílé Saulu àti ìdílé Dafidi: agbára Dafidi sì ń pọ̀ sí i, ṣùgbọ́n ìdílé Saulu ń rẹ̀yìn sí i.
Compare
Explore 2 Samuẹli 3:1
2
2 Samuẹli 3:18
Ǹjẹ́, ẹ ṣe: nítorí tí OLúWA ti sọ fún Dafidi pé, ‘Láti ọwọ́ Dafidi ìránṣẹ́ mi lé mi ó gba Israẹli ènìyàn mi là kúrò lọ́wọ́ àwọn Filistini àti lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá a wọn.’ ”
Explore 2 Samuẹli 3:18
Home
Bible
Plans
Videos