1
2 Kọrinti 10:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Àwa ń sọ gbogbo èrò àti gbogbo ohun gíga ti ń gbe ara rẹ̀ ga sí ìmọ̀ Ọlọ́run kalẹ̀, àwa sì ń di gbogbo èrò ní ìgbèkùn wá sí ìtẹríba fún Kristi.
Compare
Explore 2 Kọrinti 10:5
2
2 Kọrinti 10:4
Nítorí ohun ìjà wa kì í ṣe ti ara, ṣùgbọ́n ó lágbára nínú Ọlọ́run láti wó ibi gíga palẹ̀.
Explore 2 Kọrinti 10:4
3
2 Kọrinti 10:3
Nítorí pé, bí àwa tilẹ̀ n gbé nínú ayé, ṣùgbọ́n àwa kò jagun nípa ti ara.
Explore 2 Kọrinti 10:3
4
2 Kọrinti 10:18
Nítorí kì í ṣe ẹni tí ń yin ara rẹ̀ ni ó ní ìtẹ́wọ́gbà, bí kò ṣe ẹni tí Olúwa bá yìn.
Explore 2 Kọrinti 10:18
Home
Bible
Plans
Videos