1
2 Kronika 18:13
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ṣùgbọ́n Mikaiah wí pe, “Gẹ́gẹ́ bí ó ti dájú pé OLúWA ń bẹ láààyè, èmi yóò sọ ohun tí Ọlọ́run mi sọ.”
Compare
Explore 2 Kronika 18:13
2
2 Kronika 18:22
“Bẹ́ẹ̀ ni nísinsin yìí OLúWA ti fi ẹ̀mí èké sí ẹnu àwọn wòlíì rẹ. OLúWA sì ti sọ ibi sí ọ.”
Explore 2 Kronika 18:22
3
2 Kronika 18:20
Ní ìparí, ni ẹ̀mí kan wá síwájú, ó dúró níwájú OLúWA ó sì wí pé, ‘Èmi yóò tàn án.’ “ ‘Nípa ọ̀nà wo?’ OLúWA béèrè.
Explore 2 Kronika 18:20
4
2 Kronika 18:19
OLúWA sì wí pé, ‘Ta ni yóò tan Ahabu ọba Israẹli lọ sí Ramoti Gileadi kí ó sì lọ kú ikú rẹ̀ níbẹ̀?’ “Èkínní sì sọ tìhín, òmíràn sì sọ tọ̀hún.
Explore 2 Kronika 18:19
Home
Bible
Plans
Videos