1
1 Ọba 16:31
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ó sì ṣe bí ẹni pé ó ṣe ohun kékeré fún un láti máa rìn nínú ẹ̀ṣẹ̀ Jeroboamu ọmọ Nebati, ó sì mú Jesebeli, ọmọbìnrin Etibaali, ọba àwọn ará Sidoni ní aya, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ń sin Baali, ó sì bọ ọ́.
Compare
Explore 1 Ọba 16:31
2
1 Ọba 16:30
Ahabu ọmọ Omri sì ṣe búburú ní ojú OLúWA ju gbogbo àwọn tí ó wà ṣáájú rẹ̀ lọ.
Explore 1 Ọba 16:30
Home
Bible
Plans
Videos