1
O. Daf 97:10
Bibeli Mimọ
Ẹnyin ti o fẹ Oluwa, ẹ korira ibi: o pa ọkàn awọn enia mimọ́ rẹ̀ mọ́: o gbà wọn li ọwọ awọn enia buburu.
Compare
Explore O. Daf 97:10
2
O. Daf 97:12
Ẹ yọ̀ niti Oluwa, ẹnyin olododo; ki ẹ si ma dupẹ ni iranti ìwa-mimọ́ rẹ̀.
Explore O. Daf 97:12
3
O. Daf 97:11
A funrugbin imọlẹ fun olododo, ati inu didùn fun alaiya diduro.
Explore O. Daf 97:11
4
O. Daf 97:9
Nitoripe Iwọ Oluwa, li o ga jù gbogbo aiye lọ: Iwọ li a gbé ga jù gbogbo oriṣa lọ.
Explore O. Daf 97:9
Home
Bible
Plans
Videos