1
O. Daf 9:10
Bibeli Mimọ
Awọn ti o si mọ̀ orukọ rẹ o gbẹkẹ le ọ: nitori iwọ, Oluwa, kò ti ikọ̀ awọn ti nṣe afẹri rẹ silẹ.
Compare
Explore O. Daf 9:10
2
O. Daf 9:1
EMI o fi gbogbo aiya mi yìn Oluwa: emi o fi gbogbo iṣẹ iyanu rẹ hàn.
Explore O. Daf 9:1
3
O. Daf 9:9
Oluwa ni yio ṣe àbo awọn ẹni-inilara, àbo ni igba ipọnju.
Explore O. Daf 9:9
4
O. Daf 9:2
Emi o yọ̀, emi o si ṣe inu-didùn ninu rẹ, emi o si kọrin iyìn si orukọ rẹ, iwọ Ọga-ogo julọ.
Explore O. Daf 9:2
5
O. Daf 9:8
On o si ṣe idajọ aiye li ododo, yio ṣe idajọ fun awọn enia li otitọ ìwa.
Explore O. Daf 9:8
Home
Bible
Plans
Videos