1
O. Daf 88:1
Bibeli Mimọ
OLUWA Ọlọrun igbala mi, emi nkigbe lọsan ati loru niwaju rẹ.
Compare
Explore O. Daf 88:1
2
O. Daf 88:2
Jẹ ki adura mi ki o wá si iwaju rẹ: dẹ eti rẹ silẹ si igbe mi.
Explore O. Daf 88:2
3
O. Daf 88:13
Ṣugbọn iwọ ni mo kigbe si, Oluwa; ati ni kutukutu owurọ li adura mi yio ṣaju rẹ.
Explore O. Daf 88:13
Home
Bible
Plans
Videos